Emi Ni Ko mo wa
Mo ni BABA ni igbejo
Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono
Iya Alariya Kenke
Ti mo ban'lo pelu imo kan
Tabi mo re ko ja lo pelu inu kan
Sha de ‘de ni Blessing awa si o'do mi, tori mo gbagbo
Egbe gberu subu lotun losi mi
Nkan kan ko le se omo Olorun ……
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono
Iya Alariya Kenke
Ise owo mi, koni di ibaje
Bi wan ti e dun mo wuru mo wuru mo ‘mi
Won kon fe te, Baba ti se ileri pe ma je aye mi pe'pe'pe'pe
Ate ‘pe le'se n te ono
Ajoke aiye, asake orun…. Ko ni shi mi loo'no
Eye se inu binu simi mo, mo ni baba ni igbejo
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono
Iya Alariya Kenke