menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Méjì Méjì

Brymohuatong
smallsae80huatong
Lyrics
Recordings
Mò fí iyẹ' mi fo

Mò ri'rè

Mò wò waju mò w'oké

Ìrè dé

Kí ìjò mọlẹ mo tún takasúfè

O dún mọ' mí òó

O dún mọ' mí òó

O dún mọ' mí òó òó

O dún mọ' mí òó

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Ìfẹ rẹ sí mí o jìn gángan

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Ìfẹ rẹ sí mí ò jìn gángan

Méjì méjì làá d'àiyé ò

Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ

Mò tàràkà mo ṣubu

Kín tó kọ òun món sọ

Yàrá gbọrọ lọrá fèsì

Ẹsìn o gbani

Ìwà o lani

Òún tó wùn 'nì ló nwa ní

Ọrẹ dákun rò kò tó lọ

Mo tàràkà mo ṣubu

Kín tó kọ òun món sọ

Yàrá gbọrọ lọrá fèsì

Ẹsìn o gbani

Ìwà o lani

Òún tó wùn'nì ló nwa ni

Mó fi iyẹ mí fo

Mo rí'rè

Mó wò 'wájú mo w'òkè

Ìrè dé

Kí ijó mọlẹ mo tún takasúfè

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Méjì méjì làá d'àiyé óò

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

Méjì méjì làá d'àiyé óọ'

More From Brymo

See alllogo