menu-iconlogo
huatong
huatong
Lyrics
Recordings
Lord, I've come to seek Your face

Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord

Oh Lord, I call upon Your name

Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord

Oluwa, mo wa sibi ite

Je ki oore ofe ati aanu Re, Oluwa

Ko ba le mi lori

Oluwa, mo ke p'Oruko Re

Je ki ojo aanu Re o, Baba

Ko ro s'ori iseda mi

Baba ooooo, eyi l'ebe o

Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o (Baba ooooo, eyi l'ebe o)

Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere

(Baba ooooo, eyi l'ebe o) Ona mi to wo,

Ko di tito ninu ife Re Oluwa o, Eyi ni ebe mi o

Gba mi lowo asise, Oluwa o (Baba ooooo,

Eyi l'ebe o) Gba mi lowo ogun t'apa obi mi o ka,

Gba mi lowo ogun irandiran,

Oluwa gba mi oo Baba, Iwo ni mo gbeke mi le o, Eni to ni emi mi

Oluwa too ba to mu awon afoju san, (Baba ooooo,

Eyi l'ebe o) Oba to ji oku omo Jairu dide, Oku Lasaru,

Ojo merin, o ti n ra, o ti n run, Iwo lo ji i dide o, Oluwa saanu mi

Jesu, omo Dafidi, gbo adua mi,

Oluwa (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Baba oooo,

Oore ofe Re ni mo beere, aye o see gbe laisi oore ofe Re, Oluwa o

Mo fi oore ofe Re ra aye gbe, Oluwa (Baba ooooo, eyi l'ebe o)

Atupa imo mi ko ma se ku lailai (Baba ooooo,

Eyi l'ebe o) Iwo ni opo fitila to n tan fun emi mi Oluwa ooo

Oro Re wipe bi mo beere, ma a ri gba,

Mo n beere ki n ri gba (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Bi mo ba kan 'lekun,

Ilekun a si, ilekun ko si, a si ti ko wipe,

Bi mo ba wa kiri, ma a ri,

Mo n wa kiri, ki n ri o, ki n ni ere to po, Oluwa o

Baba Alaanu ooo (Baba ooooo,

Eyi l'ebe o) Ohun gbogbo to wa ninu iseda n gbimo aanu

Si ayanmo mi, won n sise iranwo lori ayanmo mi, Oluwa o

Ilekun si le, ilekun aanu si le, Oluwa (Baba ooooo,

Eyi l'ebe o) Aanu ro sori mi, o ro sori mi bee, Olugbebe gbo ebe mi o

Oh Lord I've come to seek Your face

Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord

Oh Lord, I call upon Your name

Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord

Oluwa, mo wa sibi ite

Je ki aanu ati oore ofe Re

Ko ba le mi lori

Oluwa, mo ke p'Oruko Re

Je ki ojo aanu Re

Ko ro s'ori iseda mi

Baba ooooo, eyi l'ebe o

Baba ooooo, eyi l'ebe o

More From Sola Allyson

See alllogo