menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Olorun Awon Omo Ogun Master

Sola Allysonhuatong
octavistoppshuatong
Lyrics
Recordings
Ògo ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ògo Ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọba tó f'amo mo wá

Ọba tó lẹ' mi wá

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun

Ọba t'ó f'amo mo wá

Ọba t'ó lẹ' mi wá o

Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún

Níbi tó lẹ'wá julo ni Ìwọ gbé

Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o

Imọ'lẹ' láṣọ re

Ọlá lo fi ṣá'so bora

Níbi tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé

Lórí obiiri ayé ni'wo wá o

Imọ'lẹ' láṣọ rẹ

O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò

Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o

Ọba tó lẹ' mi mi

Ọba tó ní gbà mi

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o

Ọba tó lẹ' mi mi

Ọba tó ní gbà mi

Ahhhhh Ahhhhh

Ìwọ lọ lèmi mi ò

Ìwọ lo nígbà mi

Ìṣẹ'lẹ' inú ìṣẹ̀dá nṣá'fihàn àgbàrá rẹ

Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o

Pẹ'lú ifilelẹ' tí ó lè Páráda láì láì

Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́n

Ṣe bí èyí tà ri là ń wi

Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye

Àìmọye làwọn tá kan n mo l'àrà

Ẹ'dá ó lè ṣá kàwé wọn

Ibí tó lẹ'wá julo ni ìwọ gbé

órí obiiri ayé ni'wo wá o

Imọ'lẹ' láṣọ rẹ

O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò

Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi

Ọba tó lẹ' mi mi

Ọba tó ní gbà mi

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh

Ọba tó lẹ'mi mi

Ọba tó ní gbà mi

Ògo ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ògo Ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn

Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ

Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun

Call: Àìmọye àwọn èyí tá' ó lé mọ' bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ

Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ'n bá ti ọgbọ'n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún

Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún

Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ

Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún

Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ' á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì

Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogun

Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní

Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

More From Sola Allyson

See alllogo