menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Alelúyà Méje

Brymohuatong
pinksweetie09huatong
Letras
Grabaciones
Aleluya Méje Méje

Oselu pé jọ f'ọjọ Méje

Won fẹ tó'lú lójó Méje

Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese

Aleluya Méje Méje

Awon Ojelu Ferege

Won L'awọn Ọmọ Yepa Tún Ti De

Wọn fẹ dá'lúrú m'èrè lè

Aleluya Méje Méje

Akonileru Wọn Tún Ti De

Wọn Fẹ sọ bo'ṣè má máa Gbe

Iwo F'okun S'ọrun òun Ṣiṣẹ Agbe

Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese

Wọn L'awọn Omidan ló m'àiyé lè

Wọn Fe Jeka, Wọn Fẹ Roso

Oko ló m'àiyé Ọkùnrin Lè

B'oko Waju Si e K'ota

Bo Ba K'eyin Si e K'ota

Bo Ba kú 'wọ Nìkàn Se Ohun Olese

Ma gbàgbé ibí O Ti n'babọ' o

B'oko Waju Si e K'ota

Bo Ba K'ẹyin Si e K'ota

Bo Ba Kuwo Nìkàn Se Ohun Olese

Ma gbàgbé ibí O Ti n'babọ' o

Aleluya Méje Méje

(Arere epa epa)

Adaleru Won Tun Ti De

(Arere epa epa)

Kofe k'ọmọ O mo Bàbá Rẹ

(Arere epa epa)

Kofe k'ọkọ O gbọ t'àyà rẹ

(Arere epa epa)

Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese

(Arere epa epa)

Won L'awọn Omidan Lomayele

(Arere epa epa)

Wọn Fe Jeka Wọn Fẹ Roso

(Arere epa epa)

Oko ló m'àiyé Ọkùnrin lè

(Arere epa epa)

Eh ya yah ya...

Más De Brymo

Ver todologo