(Zed)
Ahn-ahn
Alákóri, alakọkọ, s'ómá fẹ mí? S'ómá là tán?
Tí ń bà gbé wá (whoo), s'oma ká kò?
Ṣé mọ máa ní problem pẹ'lú boys?
Ta bà já, ká padà, má sá ló Canada
If I travel today, kí ń má bà é l'ababa (l'ababa)
Army man na my army man
Army man na my brother man
Ó lè ní problem
Ahh, baby, s'ówá pá oh? (Sówá pá?)
Sọ need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lọ máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin popping, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri nbẹ oh-yeah, oh-wururu rarurábà
(S'ọwá?)
S'òní capital business? (S'ọwá?)
S'òní character deaconess? (S'ọwá?)
Can you wake up around 4:30 (s'ọwá?)
To make breakfast for me? (S'ọwá?)
Tó bà dálè, s'olè gimme-gimme? (S'ọwá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì? (S'ọwá?)
Gimme-gimme, k'oma gbonmi jigi (S'ọwá?)
Oh-ooh-oh
Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yah
Ò ká mí mó corner (sho')
Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh)
Very gentle girl (whoo)
I'll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl)
Mama say "I don fall in love"
And my papa say "ọmọ, jẹun lọ"
Ahh, baby, s'ówá pá oh? (Sówá pá?)
Sọ need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lọ máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin popping, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri nbẹ oh-yeah, oh-wururu rarurábà
(S'ọwá?)
S'òní capital business? (S'ọwá?)
S'òní character deaconess? (S'ọwá?)
Can you wake up around 4:30 (s'ọwá?)
To make breakfast for me? (S'ọwá?)
Tó bà dálè, s'olè gimme-gimme? (S'ọwá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì? (S'ọwá?)
Gimme-gimme, kò má gbonmi jigi (S'ọwá?)
Oh-ooh-oh
(S'ọwá?)
(S'ọwá?)
(S'ọwá?)
(S'ọwá?) oh-ooh-oh
(S'ọwá?)
(S'ọwá?)
(S'ọwá?)
(S'ọwá?) oh-ooh-oh