(Oniyoungi o)
(Ayo, Ayo Maff)
Iwọ ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
I wrote you a love some, Orimọlade
Ah, joromi, ṣo ri ibi ti ta ba de
I go be your Young John, my Aquafina
Mo ti sa lọ fun Sarafina
Your love is a movie, I be Yemi Solade
Ọmọ, mo le sọnu if you no go follow me
Duro demi lọna ọja, igbawo lo ma de?
Ọmọ, mo le sọnu if you no go follow me
Igbalode baby, mo fẹ ko ni nice night
Igbalode baby, mo fẹ ko ni nice night
Iwọ nikan Ọlọlade mi, mo ba rode
Iwọ nikan Ọlọlade mi, mo ba rode
O ya o ooo
O ya o ooo
Iwọ ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
Mo wa inu tubu, mi o le jade
If love is a crime, mo wa inu tubu
Oh, I'm in chains, mi o le sare
Your love is a crime, mo wa inu tubu
Normally, I be ọmọ oro, I no be lover boy
Ki n to pade joromi, I be ọmọ oro
I be gangster, I no be lover boy
Ki n to pade joromi, I be ọmọ oro
I go feel alright to ba gbe mi si aya rẹ
Olomi, kọ'ju sọkọ, ṣo mọ?
I go see more light, iwọ ṣa ni NEPA mi
But olomi, sọ mi s'okunkun ọwọ
And I did notice some other things
If you mix Red Bull and Remy Martins
It makes me hyperactive, I dey jogodo
Wa ri mi lọla, joromi, ma ba mi ja
Igbalode baby, mo fẹ ko ni nice night
Igbalode baby, mo fẹ ko ni nice night
Iwọ nikan Ọlọlade mi, mo ba rode
Iwọ nikan Ọlọlade mi, mo ba rode
O ya o ooo
O ya o ooo
Iwọ ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
(Oniyoungi o)