(Kill dem all)
I'll run kilometers, if you are very far, ah
Stay on key, do-re-mi-fa ah, even bo lọ America
Ṣo mọ pe o má n dùn when you bọ s'inú iyára?
O joromijo, do me jara
Amdallah, you're my desire
Ah, gbogbo (gbogbo)
Gbogbo bo ṣe n jo disco, ye, mo r'ogo
I can't lie, bó ṣe n ṣe ni slo-mo, make me loco
So'di wùké, your body wicked
Loving you is unlimited, oh-ah, uhn-hun
To ba wa mi wa'le, o kuku ni sọ
Ah, ma lọ ba mi ja, ay, Olufunmi, jọọ ọ
Ma lọ ma gbé mi sáré, lo side àwọn Chibuzor ọ-ọ, ah
'Cause of Veronica, ma-ma ba mi ja
Ibadi ṣa ni, ṣa n'ìjo wa
You fit dey under my umbrella
And I won't do the things that you don't like
Anything you say, girl, I won't mind
Your body ṣa n'ìjo wa (your body ṣa n'ìjo wa)
B'áwọn body, ṣo wa?
Oló mi ma lera (ma lera), and I promise you to do better
O ya, gbogbo (gbogbo)
Gbogbo bo ṣe n jo disco, ye, mo r'ogo (ye, mo r'ogo)
Ọmọ, bó ṣe n ṣe ni slo-mo, make me loco
I'm so addicted, your body wicked
Loving you is unlimited (mm, uhn-ah-ah, ah)
To ba wa mi wa'le, o kuku ni sọ
Ah, ma lọ ba mi ja, ay, Olufunmi, jọọ ọ
Ma lọ ma gbé mi sáré, lo side àwọn Chibuzor ọ-ọ, ah
'Cause of Veronica, ma-ma ba mi ja
Ibadi, ibadi, ṣa n'ìjo wa
Pounds sterling, o wa
And I won't do the things that you don't like (whoa, oh)
Ṣebi ibadi, your body ṣa n'ijo wa
You fit dey under my umbrella
Ṣo like Porsche Panamera?
(Kill dem all)