It's Fierce Nation
Lekan
Vibe
Eeyan Laycon
It's Conny Sir
Wọn ti fi wave si
This na the song for the man dem
Ọja, haha
Ṣo ri pe bayi (ṣo pe bayi)
Ṣebi ẹ n ba mi sọrọ (ba mi sọrọ)
Awọn ẹruku yapa, jaapa, t'ọn ba mu ẹ n kọrọ
Ṣebi ẹ n wa mi? (Ṣebi ẹ n wa mi?)
Wọn fẹ ba mi sọrọ (ba mi sọrọ)
Tell mama mi
Ay, t'ọn ba n ba mi sọrọ
Awa fierce
Awa fierce
Awa fierce
Awa fierce (switch it up)
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa (okay, okay)
So, me, I look like the type of guy you could talk to?
Uh-uh, don't let me fool you (yeah)
I'm god body, so I don't like the Devil (nah)
Don't let him use you (okay)
Ṣebi dem dey give me apologies
They want forgiveness, I be givin' too (fierce)
Anythin' you need I could give in twos (fierce)
My temper, I never wanna loose, uh-uh
Ṣebi you know say I ready
I go still dey give you the energy, uh-uh
Better be ready for war
'Cause we comin' with fury, we menacing, uh-uh (okay, okay)
My wolf pack over everythin' ('thing)
That's fierce nation over anythin' ('thing)
Bọbọ, all my - be fierce
Why you think say we win everythin'?
Ṣo ri pe bayi (ṣo ri pe bayi)
Ṣebi ẹ n ba mi sọrọ (ba mi sọrọ)
Awọn ẹruku yapa, jaapa, t'ọn ba mu ẹ n kọrọ
Ṣebi ẹ n wa mi? (Ṣebi ẹ n wa mi?)
Wọn fẹ ba mi sọrọ (sọrọ)
Tell mama mi
Ay, t'ọn ba n ba mi sọrọ
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa
Ẹruku nla-nla, Tiger
Everybody lo mọ pe mo ya wèrè gan-an
Wọn dẹ mọ pe mo fierce (wọn dẹ mọ pe mo fierce)
Ma ni k'ogun ọrun jọọ, ba mi kan ẹ n'iko
To ba fẹ fun mi stress (stress)
I put all my problems behind me, maa f'ẹyin, jọọ
And I clean up my tears
And I say, "Nevertheless
Oriburuku no go know my address"
Ki lo de? (ki lo de? Ki lo de?)
Why you dey hate on me?
You can never stop the blessing
He dey shine on me
Ẹni to ba sa aṣọ s'ita (ẹ kaa)
Tẹ ba ti gb'ohun popo (ẹ yaa)
Ẹni to ba m'owo k'ọwọ (ẹ ṣa)
Ẹni to ba lọwọ epo (ẹ laa, ẹ laa, ẹ laa)
Ṣo ri pe bayi (ṣo ri pe bayi)
Ṣebi ẹ n ba mi sọrọ (ba mi sọrọ)
Awọn ẹruku yapa, jaapa, t'ọn ba mu ẹ n kọrọ
Ṣebi ẹ n wa mi? (Ṣebi ẹ n wa mi?)
Wọn fẹ ba mi sọrọ (sọrọ)
Tell mama mi (tell mama mi)
Ay, t'ọn ba n ba mi sọrọ
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa mi
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa
Awa fierce gan-an t'ọn ba n wa wa
Emi fierce
Wọn wa mi, wọn ri mi (Ìbílẹ')
Ah-ah, to ba ya wọn ma sin mi (whoo, whoo, whoo)
Irẹsi wọn ṣi ma ji mi
To ba ri mi, wọn ma ki mi
Mo fierce gan-an, I fit be lion (lion, lion)
Mo ti bawọn lo g'oke Mount Zion (whoo, whoo, whoo)
Ọmọ onile ti de, jẹ k'ori pe o
Fila to bojumu ni kori de o
Mo dẹ gbadura pe ko ma ri ṣe o (ah, ah)
Ma lọ Maradona bi Nini de o (whoo, whoo)
Ijaya, ijaya, ma lọ jawa, jawa
'Cause you already know all the yawa, yawa
Tori level nla dẹ lemi ba wa, ba wa
If not, I will turn your sweet to sour, sour
Ìbílẹ', oninu mimọ, akanchanwa
Akanchanwa (awa fierce)
Ṣo ri pe bayi (ṣo pe bayi)
Ṣebi ẹ n ba mi sọrọ
Awọn ẹruku yapa, jaapa, t'ọn ba mu ẹ n kọrọ
Ṣebi ẹ n wa mi? (Ṣebi ẹ n wa mi?)
Wọn fẹ ba mi sọrọ
Tell mama mi
Ay, t'ọn ba n ba mi sọrọ
Awa fierce
Focus (Focus)