(M-M-Muderer)
Them cover their head, carry AK twen'
I don't know the thing you una dey call am, AK25 (AK47)
Yes, them say make we no talk
I say, na lie, my daddy G.O say I will talk
Correct, I will talk, I am a chosen
I am a chosen (I am a chosen)
I am a chosen, you wicked man, who are you? (I am a chọ-chọ)
Ay, ẹni t'Ọlọrun pé l'Ọlọrun yàn
Ko to di wo-wo-wo (kò to di wo-wo-wo)
Ọmọ Ọlọhun ń gbọ (ọmọ Ọlọhun ń gbọ)
Ọlọhun ń gbọ ó (ọmọ Ọlọhun ń gbọ ó)
Ọmọ Ọlọhun ń gbọ (ọmọ Ọlọhun ń gbọ)
I wan give testimo-, I get one testimony
I wan give testimo-, I get one testimony
Mo wá dupẹ to ko mi yọ
O tún jẹ k'okó mi yọ, hm-hm, o ṣe
Yee, Bilikisu, máa do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada
Èlò ni mo gbà ti má gbé raga?
I wan give testimo-, I get one testimony (elò ni mo gbà ti má gbé raga?)
I wan give testimoo, I get one testimony (elò ni mo gbà ti má gbé raga?)
Eh, èmi ó ṣákọ mọ o (uh fafa lé wọn)
Emi ó ṣákọ mọ o-o (uh fafa lé wọn)
Normally, na wake and bake up
Call my dealer, e never wake up
Mo ṣì crusher, mo ri igbẹ ẹṣin
Miracle working Jesus
Genesis touch my heart o
Exoduxe burst my brain oh
After this one (after this one)
Emi o mu igbó mọ ó (emi o mu igbó mọ ó)
I wan give testimo-, I get one testimony
Mo wá dupẹ to ko mi yọ
O tún jẹ k'okó mi yọ, hm-hm, o ṣe
Yea, Bilikisu má do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada
Èlò ni mo gbà ti má gbé raga?
I wan give testimo-, I get one testimony (elò ni mo gbà ti má gbé raga?)
I wan give testimo-, I get one testimony (elò ni mo gbà ti má gbé raga?)
Eh, emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Eh, emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Eh, emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó ṣákọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Who mix this? (M-M-Murderer)
(Whoo)