menu-iconlogo
logo

2:30

logo
avatar
Asakelogo
smokin_allday_laosbologo
Cantar no App
Letra
Lyricist : Ahmed Olalade Asake/Olamide Adedeji

Composer : Ahmed Olalade Asake/Olamide Adedeji

Uh

Obah

What dem a say?

Obah

Run

Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm

Awa de, awa de de

Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye

Orimọlade gbemi debẹ

Jigan jigan

Ẹsẹ mi o delẹ, delẹ

Alaye mi stop shebẹ

O fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ

Opọ se

Agbawo, fẹnu fo fence

Sun sẹ yin

Amọrawa, sho get?

Abinibi yato s'ability

Ẹsọ fun wọn tan ba teri si

Wọn ma pa lori

Tẹnu kọ, emi promising

Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi

Tori ko sẹ lomi

Many many fẹ dabi mi

Eri bi

Ẹgbọlorun tobi

Mo da aso-ẹbi for my country

You can call me Mr Money

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

Ye, ye, ye

2:30 fẹlu (Thirty fẹlu)

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

Ere moba wa kosi ja

Shokoto pen pe, ye

Ayenika, yebo, yeba

Formation logba, ye ja

Ọmọ'yami ko stay wise

Tranquility, tranquility

I no get time to dey form activity

Kole kalas, I dey find stability

Like abacha, monеy long infinity

What's the chances?

What's the probability?

To see a bеtter version of me with agility

No you can't fake reality

Ogun, principality and calamity

Mo ti lọ, mo ti pa iyen ti

Bẹbẹ no de for jiji

O shi wa n titi

Still get money like Fifty

Dripping like Fiji

I be real G

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

2:30 de Asake – Letras & Covers