menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Awuyewuye

Diamond Jimmahuatong
rburawskihuatong
بول
ریکارڈنگز
(Boss)

Jummy

Jummy, Jummy, w'oju mi (w'oju mi o)

Ikebe sọkutu wọ, wọ, wọ

O ṣe mi bi gan, gan, gan

Ko si iru ẹ ri, Ọlọrun gbọ

Ifẹ rẹ da mi lọrun gan-an

Mo fẹ fi ẹ ṣ'aya mi lọrọ-kan

Ojojumọ lo n yọ bi o ọjọ

Iwọ mo fẹ mari, o l'ẹnikan

O pa mi, o pa mi, o ye, mo fọ

Whether you be Igbo or Hausa, Yoruba, e no matter

Can I know your name, ọlọmọge? Ma ṣe gapa

I go pay you my cash

Ṣe na lion? Mo ma pa

Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comoti wrapper

Awuyewuye o, awuyewuye

Awuyewuye o, awuyewuye

Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga

Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ

Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye)

Awuyewuye o, awuyewuye

Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga

Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ

W'oju mi, wo'nu mi

Sọ fun mi, ma j'oju mi

Ko ni su mi, ẹyinju mi, fara mọ mi

Ko s'ẹni to le fun mi, ifẹ rẹ dun bi oloyin

Bi mo ri ẹ, o ti yo mi

Jọọ, ma ṣe kan'ra mọ mi

Whether you be Igbo or Hausa, Yoruba, e no matter

Can I know your name, ọlọmọge? Ma ṣe gapa

I go pay you my cash

Ṣe na lion? Mo ma pa

Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comoti wrapper

Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye)

Awuyewuye o, awuyewuye

Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga

Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ

Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye)

Awuyewuye o, awuyewuye

Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga (ọmọge)

Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ

Ah, ah-ah-ah, ah, mo de

W'oju mi, ẹyinju mi

Ọmọ Abẹokuta re wa o

O ma gba dandan-an ni

E si un o ma ṣe

Diamond Jimma کے مزید گانے

تمام دیکھیںlogo
Awuyewuye بذریعہ Diamond Jimma - بول اور کور