menu-iconlogo
logo

7 DAYS

logo
Lời Bài Hát
Gbogbo owó tí mo na (oya, oya, move)

Fún ọjọ' méje (ko, kober!)

Gbogbo owó tí mo na

Kò gbe ogungunnisọ fún mí

Èmi ọmọ oró, I no fit pass my lane

Wọn ni kin ma jáde, but wọn lé mi

Èmi ọmọ owó, I no do pass myself

Wọn ni kín má sáré, but wọn le mi-i

So, I can not see my brother Ojo (Ojo o...)

And popo them don lock my brother up o

Say, make them free my brothers, oh-oh

Them no kill person, them be ọmọ owó, oh

Ajé ogugulusọ o (ah, o kúkú ni sọ fún mi)

Ah, o kúkú ni sọ fún mi (ah, o kúkú ni sọ fún mi)

Ah, o kúkú ni sọ fún mi (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi)

Mo mọ pe o kúkú ni sọ fún mi

Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje

Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ

Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje

Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ

Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi

Ki ọta mi le ri ran wo

Ki ọta mi le ri ran wo

Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa

Ki ọta wá le ri ran wo

Ki ọta wá le ri ran wo

Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi

Ki ọta mi le ri ran wo (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi)

Ki ọta mi le ri ran wo

Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa

Ki ọta wá le ri ran wo

Ki ọta wá le ri ran wo

I've been thinking, I've been too deep in my feelings

Bless my pocket, ṣé mi l'ọmọ t'ọ ma jí ri

If I no hustle who go take care of my siblings

If I no hustle who go take care of my siblings

Mo sare wọ Jerusalem, mo gbàdúrà ki n le pa'wo

If ọlọ́pàá no lock Ojo up, my brother he dey yawo

Man make man kàlà

Ẹjẹ lo jú mi

Man make man kala, ah

Ẹjẹ lo jú mi

Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje

Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ

Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje

Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ

Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi

Ki ọta mi le ri ran wo

Ki ọta mi le ri ran wo

Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa

Ki ọta wa le ri ran wo

Ki ọta wa le ri ran wo (koba!)