menu-iconlogo
logo

Happiness

logo
歌词
Àlàyé mí bá mí sọrọ kàn, kí lo ń lọ? (Kí lo ń lọ)

For my area, ọrọ mí lọ ń sọ (lọ ń sọ o)

Wọn ní mo give them pressure, pressure

Ò jẹ máà lọ sún, ṣíṣẹ lọ

Ọmọ ìyá, pá'wó lọ

Nobody go dey when sapa don too much

Ẹnì to bà bá ṣ'òun ṣa lo mọ

Kabo, kabo lọ, ọmọ'ba ṣìn lọ

E still dey lit, but e still dey hot

Happiness, ẹ rí finesse

My life no stress, fine boy, no ex

Happiness, ẹ rí finesse

My life no stress

O tútù, o tútù, o wọ 'yin o

Má gara sí mí, alakori o

Òun to ń se yìn kọ lo ń ṣe mí o

Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe,I no be novice

Yepa,yepo,àṣàmọdi o

Ọga, no dey form over sabio

Michael Scofield, as you can see

I be zombie, sir, kò kàn mi o

O tútù, o tútù, o wọ 'yin o

Má gara sí mí, alakọri o

Òun to ń se yìn kọ lo ń ṣe mí o

Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe,I no be novice

Yepa,yepo,àṣàmọdi o

Ọga, no dey form over sabi o

Michael Scofield, as you can see

I be zombie, sir, kò kàn mi o

Got your birthstone, you a earth tone

I miss you, need you bad, baby, come home

You want me, make it happen, baby, I know

Want me to keep you happy, baby, I know

Penthouse, and a condo

Got no one, amapiano

You want me, make it happen, baby, I know

I'm here to make you smile when you feel low

Happiness, ẹ ri finesse

My life no stress, fine boy, no ex

Happiness, it's a feeling

Your life no stress

O tútù, o tútù, o wọ 'yin o

Má gara sí mí, alakọri o

Òun to ń ṣe yìn kọ lo ń ṣe mí o

Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe,I no be novice

Yepa,yepo,àṣàmọdi o

Ọga, no dey form over sabi o

Michael Scofield, as you can see

I be zombie, sir, kò kàn mi o

Happiness Gunna/Asake/Sarz - 歌词和翻唱