menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Àjítannáwò

Sola Allysonhuatong
snapyoureithuatong
歌词
作品
Eni à ba ta k′a fi r'atupa ni mi

Ajitannnawo ti mo da ope l′o ye'Lu

O to mi s'ona t′o ye n gba t′Oba l'ope

Ade, o de mi mo gbe kale niwaju Re

Mo te′ri okan mi ba o s'Olorun mi

(Enia bata)

Eni à ba ta k′a fi r'atupa ni mi

Ajitannnawo ti mo da ope l′o ye'Lu

O to mi s'ona t′o ye n gba t′Oba l'ope

Ade, o de mi mo gbe kale niwaju Re

Mo te′ri okan mi ba o s'Olorun mi

Ajitananwo ti mo da (ope mo mu wa)

Ajitannawo ti mo da (ope mo mu wa)

Irugasoke ko rara (mo s′ope f'Olu)

Anu mo ri gba (eni ko o ope)

Irugasoke ko rara mo s′ope f'Olu

Aanu mo ri gba emi ko ope

Iboju ya ewon bo eru mi fuye

Ile oro ti mo wo ope

(Eni a bata)

Eni à ba ta k'a fi r′atupa ni mi

Ajitannnawo ti mo da ope l′o ye'Lu

O to mi s′ona t'o ye n gba t′Oba l'ope

Ade O de mi mo gbe kale niwaju Re

Mo te′ri okan mi ba o s'Olorun mi

Ago igbala ni mo gbe ope

Maa polongo oro yi titi

Kos'ohun to wa ti Baba ò le tan

Eni wa l′eyin ogba yara wole

Iboju á ya ewon á bo eru re a fuye o

Agbo igbala l′emi gba ope!

(Eni a ba ta)

Eni à ba ta k'a fi r′atupa ni mi

Ajitannnawo ti mo da ope l'o ye′Lu

O to mi s'ona t′o ye n gba t'Oba l'ope

Ade O de mi mo gbe kale niwaju Re

Mo te′ri okan mi ba o s′Olorun mi

Ajitannawo ti mo da (ope)

Ajitannawo ti mo da (ope)

Aanu Oluwa lo gba mi o (ope)

Ko jo pe bayi laa ri o (ope)

Yiyo Eleda ni mo ri o (ope)

Fun gbogbo anfani ati iranwo ti mo n ri lo (ope)

Aanu po l'odo Baba wa (wa)

Eni wa l′eyin ogba wole wa o (wa)

Iwo naa wa o si wa (wole)

Iwo naa wa yara maa bo (Wole)

Irira t'o bà sori ogo (a tan)

Idamu t′o wa lori ogo (a tan)

Iwenu a sele omo o (waa no)

Okun a ja, ewon a bo, iboju a ya

Iri a se s'ori ogo (itura a de)

Imuse a wa itura a wa (itura a de)

Ajitannawo ti mo da (ope)

Ago igbala ti mo gba (ope)

更多Sola Allyson热歌

查看全部logo