menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Ife

Sola Allysonhuatong
deeandboo1huatong
歌詞
作品
Iwo lo ye

Ogo Ola

Iwo lo ye

Iyin Eye

(Iwo loye o)

Iwo lo ye

Ogo Ola

Iwo lo ye

Iyin Eye

Iwo l'ope to si

Oba mimo

Iwo niyin to si

Oba toto

Ikawo Re

Lohun gbogbo ti wa

Iwo lo ye

Ogo Ola

Iwo lo ye

Iyin Eye

Iwo lo ye

Ogo Ola

Iwo lo ye

Iyin Eye

Iwo l'ope to si

Oba mimo

Iwo niyin to si

Oba toto

Ikawo Re

Lohun gbogbo ti wa

Iwo lo ye

Ogo Ola

Iwo lo ye

Iyin Eye

Kabiyesi o Eledumare

To to to Oba

Kabiyesi o Oba to joko lori obiri aye Ogo fooko Re

To to to Oba

Iba Re Iba Re to to to

To to to Oba

To to to Oba

Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo

To to to Oba

Kabiyesi o, awon orun n soro ogo Re, ofurufu n fise Re han

To to to Oba

Ise Re po gaan ni ko lafiwe o, a wole a fiyin foruko mimo Re

To to to Oba

Kabiyesi o, Baba mi, Olorun mi, Eni to lebun gbogbo

To to to Oba

Iba Re, iba, iba, to to

To to to Oba

To to to Oba

Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo

To to to Oba

Oba Ibere

Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo

To to to Oba

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Baba to lemi mi ogo fooko Re

Iwo ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Alagbara kan ko ma si

Onimo kan ko ma ma si o

Ko si o o o

Ko si leyin Re

Iwo l'Oba to lemi mi Iwo ni

Iwo saa ni maa fi gbogbo igba mi gbe ga o

Ko selomiran leyin Re

Ko si o

Ninu aso igunwa t'O fi se mi loso mo ba ruburubu

Mo foribale fooko Re o

Iwo saa ni Ologbon julo

Ko si o (ko si o)

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

A se ite fun O ninu okan wa Iwo ni

Iwo ni Baba to ju baba lo

Inu orin iyin awon eni mimo niwo n gbe Baba

Iwo ni Baba to ju baba lo

Oba to joko lori ite, awon angeli n foribale fun O

Iwo ni Baba to ju Baba lo (Eyin ni)

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eyin ni Baba to to baba

Eyin ni Baba to ju baba lo

Eeeh e wa, e wa woran o

Baba wa ni

E wa w'Alewilese o

Baba wa ni

Alagbawi awa o

Baba wa ni

Oba to tan 'mole sona wa, Oun ni

Baba wa ni

Aye si n be, elese wole wa

Baba wa ni

Baba wa po ni agbara, O po ni aanu o

Baba wa ni

Eh eh eh ah e lo simi agbaja

Awa ni Baba kan to moye

Oun lo tun le aye awa se ge ge

Eh eh eh eh eh eh ah

Eh eh eh ah e lo simi agbaja

Awa ni Baba kan to moye

Oun lo tun le aye awa se ge ge

Eh e wa e wa woran o

Baba wa ni

E wa wo Olurapada Alaanu to n tu ni sile

Baba wa ni

E wa wo Alara ire Oba to n tun ni se

Baba wa ni

Eni to wa leyin ogba ko wole wa

Baba wa ni

Aye si n be ninu ogba Alaanu o

Baba wa ni

B'omode sun, a fi isori E so

Baba wa sun, a fi isori E so

Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu

Hallelujah Ogo ni fun Baba

Ki la fi san j'awon t'iku ti pa

Ire lo s'aabo, alaafia wa

Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu

Hallelujah Ogo ni fun Baba

Oh oh oh oh Allelu...

Hallelujah Ogo ni fun Baba

A ti ri 'gbala ojo oni

Alaaye ni yoo yin O bo ti ye

Hallelujah Ogo ni fun Baba

A a a a a a allelu...

Hallelujah Ogo ni fun Baba

A fijo filu yin Olorun wa

Alaaye ni yoo yin O bo ti ye

Hallelujah Ogo

Oluwa ooo

Eh eh

Oluwa ooo

Eh eh

Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa

Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa

Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa eeeh

Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa

Ope ye O ooo eh

Ope

Eni to joko lori ite ogo fooko Re

Ope

Ope ye O ooo eh

Ope

Ope ye O ooo eh

Ope

Ope ye oruko Re Iwo nikan ni

Ope

Ko si o

Tani n ba sin bi o se 'Wo

Oba to f'aanu tan 'mole sona mi

Ko s'elomii leyin Re

Orin yi naa ni emi o maa ko

Orin irapada imole t'O tan fun mi

Aanu n mo ri gba, ookun pada di'mole lona mi

Ko si leyin Re

Ajoda ope la da

Iyin sa la mu wa

Ajoda ope ni gbogbo iseda da

Iyin sa la mu wa

F'Oba to Lola

Olu sola to fun ni lola se

Olupenisola

Ogbenuenisola

Ta lo le sola

Lai se p'Oo fun lola se

Ola Re lo n fun ni lola

T'aa fi n sola ninu Re

F'Oba to fun ni lai gbebo o

Ope la mu wa

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Alagbara kan ko ma si

Onimo kan ko ma ma si o o o o

Ko si ooo

Ko si leyin Re

Iwo ni ma ma yin lojojumo

Iwo ni maa fi aye mi gbega o

Ko selomiran leyin Re

Ko si o eeee

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

Ko si o

Ko si o

Ko si o

Ko si leyin Re

更多Sola Allyson熱歌

查看全部logo