menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Imole II - (Acoustics)

Sola Allysonhuatong
slinda.george11huatong
歌词
作品
Jesu! Imole!

Ategun ati Afara

S'ibi Imole

Jesu! Eni t'O wa

Ife Baba

S'eni to fe d'omo

Jesu! Imole!

Ategun ati Afara

S'ibi Imole

Jesu! Eni t'O wa

Ife Baba

S'eni to fe d'omo

Jesu! Imole!

Ategun ati Afara

S'ibi Imole

Jesu! Eni t'O wa

Ife Baba

S'eni to fe d'omo

Imole, lati 'nu Imole

O wa lati da wa pada

S'ona Imole

Ookun to gb' aye

Ko je k' 'on mo Imole

Won dite mo O, Ife Baba

Olorun ninu eniyan

Eniyan ninu Olorun

Ilekun awon aguntan

S'inu ile aanu

Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s'odo Baba

B' aye ti n fi fun ni ko

Imole s'ookun aye mi

Olu se 'wosan emi mi

Jesu! Imole!

Ategun ati Afara

S'ibi Imole

Jesu! Eni t'O wa

Ife Baba

S'eni to fe d'omo

(Emi mi ke rara, mo pe Jesuuu!)

Jesu! Imole!

Ategun ati afara

S'ibi Imole

Jesu! Eni t'O wa

Ife Baba

S'eni to fe d'omo

Eni wa Imole

Won n ri Imole

Won o mo Imole

Won n dite Imole

Irora yen po gan

Eje at' omi san gan

Sibe O s' agbawi fun wa

Pe Baba dariji won

Won o mo n t' 'on se

S' a ti mo 'n a n se

Baba, dariji wa o, nitori Imole

Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole ***

O ni "Iya wo omo re, Omo wo iya Re"

O kigbe lohun rara:

"Olorun mi, eese t' O ko mi i le..."

"Eese to ju mi le, eese t' O yin mi nu?"

Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un

Awon to wa Imole o, won fi 'ya je Imole

O ba pari, O pari!

Imole f' emi E s'owo Baba

O pari!

Nitori Imole

Aso ikele ya o

Nitori Imole

A le pe Baba ni Baba

Nitori Imole

Isa oku d'ofo

Eni ba fe le wa d'omo

Jesu! Oga Ogo!

Olori Ogun Orun!

Omo Alade Alaafia!

Alase Orun!

Aye Baba!

Baba laaye o!

Baba laye!

Aye mi, Tire ni

Tan Imole nipase mi

Ogo mi k'o f'ogo fun O

Ola mi k'o bu ola fun O!

Jesu! Iwo ni 'Mole!

Iwo ni Afara!

S'ibi ategun Imole

Jesu! Iwo ni Eni naa t'O wa

Mo juba Re, Eni to so mi d'omo

更多Sola Allyson热歌

查看全部logo