menu-iconlogo
huatong
huatong
avatar

Mimo

Sola Allysonhuatong
pocu_starhuatong
歌词
作品
Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Oluwa Olorun Eledumare to poo ni pa ati agbara

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Gbogbo iseda soo bee eemi na soo bee

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Lati oogun eemi mi

Mo juba re Ooba mimo

Awa ma ri di Oluwa

Mowo le fun Ooba toto

Leyin ree ko si ooo

Iwo to wa ni pekun kun imole

Iwo ni ekun ola ekun oogbon ekun agbara

Iwo nikan ni Ooba

Mo juba re Ooba mimo

Ooba to joko sori ite

Ooba to wa lori obiri aye ma se Oola re loo

Mowo le fun Ooba toto

Leyin ree ko si ooo

Aye ati Oorun nkoo ko si elomi

To ye ko gba ijuba wa bi o se Iwo

Iwo nikan ni Ooba

Mo wa ri fun ooo Oolola

Pelu iwa riri lati oogun emi mi

Imole to tan sinu okunkun mi

Ogo fun okoo re

Leyin Oluwa

Leyin ree ko si ooo

Ko se lomi Iwo ni

Leyin re Iwo na ni ma sola re lo Oluwa

Iwo nikan ni Ooba

Leyin ree ko si ooo

Olugbemiro

Olusainumi

Olukemi

Olufunmilebun

Olugbemiro Iwo ni kan

Olutimileyin Iwo ni

Iwo nikan ni Ooba

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Aye ati Oorun soro ogo re afi ise Oowo re won Iwo mimo

Mo da oun mi poo moo gbogbo ise re

Emi e imimi ati emimi ayin ooo ni gba gbogbo

Ooba to wa ni ipekun ola ipekun ogo ipekun agbara ipekun ewa

Iwo nikan ni Oluwa

Pepe na loda Oluwa

Pepe ni ooo pepe ni ooo pepe

Talo le yo koro ninu re nigba ti a ti e emo ooo

Pepe ni ooo pepe ni ooo pepe

Yiye ni ooo yiye ni ooo yiye

Iwo na lowa fun rare Iwo ni Oluwa

Yiye ni ooo yiye ni ooo yiye

Odo Agutan to Jo ko sori ite oooo yiye

Tito ni ooo eleda gbogbo eniyan

Tito ni ooo tito ni ooo tito

Olotoju gbogbo eniyan Olorun gbogbo a re

Eniti to ngbo adura odore la wa Iwo ni

Tito ni ooo tito ni ooo tito

Gigun ni ooo gigun oooo gogun

Ooba to joko so iri obi ri aye

O fi aye sole sori awon isan omi aye ole ri

Lailai kole ri ise re ni gigun oo gun Lai lai

Mo juba re Oluwa

Mo juba re oba mimo

Emi mi juba re nigba gbogbo

Mo wole fun ooo Baba

Mo wole fun oba toto

Leyin re kosi elomi

Leyin re eee kosi ooo

I confess kosi elomi Olorun Eledumare to poo ni pa ati agbara Iwo nio

Olorun awon omo ogun Iwo nikan

Iwo nikan in Ooba

Mo juba re oo baba

Mo juba re Ooba mimo

Tani ba juba bi oo se Iwo

Olori Egbegberun ogun awon angeli Iwo ni

Mo wole fun Ooba toto

Oludaye kosi le lomi

Leyin re kosi ooo

Aseda gbogbo eniyan Olorun gbogbo ede

Olorun gbogbo eya Iwo Iwo nikan

Iwo nikan ni Ooba

Mo wari fun ooo Olola

Emi mi eemi mi ati emi na

Imole tio le ku lailai

Imole to tan sinu okunkun mi

Ogo fun oko re

Lehin re (baba) kosi oooo

Olugbemiro olusanumi olugbamila oluyomi ninu okunkun

Iwo nikan ni Ooba

Lehin re kosi oooo

Tani ba sin ti o se eni tio gbamila

Eni ti mio ri sugbon ti mo ri isere ninu ayee mi

Iwo nikan ni Ooba

Olorun gbogbo araye Iwo nikan ni

Olutoju gbogbo eniyan Iwo nikan ni

Mo kio kio Iwo nikan ni Ooba

Ma shola re looo

Ma shola re looo

Ko se lo mi

You are the only one

You are the only one

Iwo nikan

Holy mimo mimo ni oo Iwo ni Ooba

Iwo nikan ni Ooba

更多Sola Allyson热歌

查看全部logo